O. Daf 78:1 YCE

1 FI eti silẹ, ẹnyin enia mi, si ofin mi: dẹ eti nyin silẹ si ọ̀rọ ẹnu mi.

Ka pipe ipin O. Daf 78

Wo O. Daf 78:1 ni o tọ