O. Daf 78:4 YCE

4 Awa kì yio pa wọn mọ́ kuro lọdọ awọn ọmọ wọn, ni fifi iyìn Oluwa, ati ipa rẹ̀, ati iṣẹ iyanu ti o ti ṣe hàn fun iran ti mbọ.

Ka pipe ipin O. Daf 78

Wo O. Daf 78:4 ni o tọ