O. Daf 86:9 YCE

9 Gbogbo awọn orilẹ-ède ti iwọ da ni yio wá, nwọn o si sìn niwaju rẹ, Oluwa; nwọn o si ma fi ogo fun orukọ rẹ.

Ka pipe ipin O. Daf 86

Wo O. Daf 86:9 ni o tọ