O. Daf 90:17 YCE

17 Jẹ ki ẹwà Oluwa Ọlọrun wa ki o wà lara wa: ki iwọ ki o si fi idi iṣẹ ọwọ wa mulẹ lara wa, bẹ̃ni iṣẹ ọwọ wa ni ki iwọ ki o fi idi rẹ̀ mulẹ.

Ka pipe ipin O. Daf 90

Wo O. Daf 90:17 ni o tọ