2 Ki a to bí awọn òke nla, ati ki iwọ ki o to dá ilẹ on aiye, ani lati aiye-raiye, iwọ li Ọlọrun.
Ka pipe ipin O. Daf 90
Wo O. Daf 90:2 ni o tọ