O. Daf 90:8 YCE

8 Iwọ ti gbé ẹ̀ṣẹ wa ka iwaju rẹ, ohun ìkọkọ wa mbẹ ninu imọlẹ iwaju rẹ.

Ka pipe ipin O. Daf 90

Wo O. Daf 90:8 ni o tọ