O. Daf 92:10 YCE

10 Ṣugbọn iwo mi ni iwọ o gbé ga bi iwo agbanrere; ororo titun li a o ta si mi lori.

Ka pipe ipin O. Daf 92

Wo O. Daf 92:10 ni o tọ