O. Daf 99:9 YCE

9 Ẹ gbé Oluwa Ọlọrun wa ga, ki ẹ si ma sìn nibi òke mimọ́ rẹ̀; nitori Oluwa Ọlọrun wa mimọ́ ni.

Ka pipe ipin O. Daf 99

Wo O. Daf 99:9 ni o tọ