O. Daf 18:43 YCE

43 Iwọ ti yọ mi kuro ninu ìja awọn enia; iwọ fi mi jẹ olori awọn orilẹ-ède: enia ti emi kò ti mọ̀, yio si ma sìn mi.

Ka pipe ipin O. Daf 18

Wo O. Daf 18:43 ni o tọ