44 Bi nwọn ti gburo mi, nwọn o gbà mi gbọ́: awọn ọmọ àjeji yio fi ẹ̀tan tẹ̀ ori wọn ba fun mi.
Ka pipe ipin O. Daf 18
Wo O. Daf 18:44 ni o tọ