O. Daf 53:5 YCE

5 Nibẹ ni nwọn gbe wà ni ibẹ̀ru nla nibiti ẹ̀ru kò gbe si: nitori Ọlọrun ti fún egungun awọn ti o dótì ọ ka: iwọ ti dojutì wọn, nitori Ọlọrun ti kẹgàn wọn.

Ka pipe ipin O. Daf 53

Wo O. Daf 53:5 ni o tọ