6 Tani yio fi igbala fun Israeli lati Sioni jade wá? Nigbati Ọlọrun ba mu igbekun awọn enia rẹ̀ pada wá, Jakobu yio yọ̀, inu Israeli yio si dùn.
Ka pipe ipin O. Daf 53
Wo O. Daf 53:6 ni o tọ