Orin Dafidi 10:15 BM

15 Ṣẹ́ eniyan burúkú ati aṣebi lápá,tú àṣírí gbogbo ìwà burúkú rẹ̀,má sì jẹ́ kí ọ̀kan ninu wọn farasin.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 10

Wo Orin Dafidi 10:15 ni o tọ