2 N óo múra láti hu ìwà pípé pẹlu ọgbọ́n;nígbà wo ni o óo wá sọ́dọ̀ mi?N óo máa fi tọkàntọkàn rin ìrìn pípé ninu ilé mi.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 101
Wo Orin Dafidi 101:2 ni o tọ