Orin Dafidi 101:6 BM

6 N óo máa fi ojurere wo àwọn olóòótọ́ ní ilẹ̀ náà,kí wọ́n lè máa bá mi gbé;ẹni tí ó bá sì ń hu ìwà pípé ni yóo máa sìn mí.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 101

Wo Orin Dafidi 101:6 ni o tọ