Orin Dafidi 102:15 BM

15 Àwọn orílẹ̀-èdè yóo máa bẹ̀rù orúkọ OLUWA,gbogbo ọba ayé ni yóo sì máa bẹ̀rù ògo rẹ̀.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 102

Wo Orin Dafidi 102:15 ni o tọ