15 ati ọtí waini tí ń mú inú eniyan dùn,ati epo tí ń mú ojú eniyan dán,ati oúnjẹ tí ń fún ara lókun.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 104
Wo Orin Dafidi 104:15 ni o tọ