Orin Dafidi 107:43 BM

43 Kí ẹni tí ó gbọ́n kíyèsí nǹkan wọnyi;kí ó sì fi òye gbé ìfẹ́ OLUWA tí kì í yẹ̀.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 107

Wo Orin Dafidi 107:43 ni o tọ