Orin Dafidi 107:8 BM

8 Jẹ́ kí wọn máa yin OLUWA nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀,àní nítorí àwọn iṣẹ́ ìyanu tí ó ṣe fún àwọn ọmọ eniyan.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 107

Wo Orin Dafidi 107:8 ni o tọ