Orin Dafidi 11:4 BM

4 OLUWA ń bẹ ninu tẹmpili mímọ́ rẹ̀,ìtẹ́ rẹ̀ wà lọ́run;OLUWA ń kíyèsí àwọn ọmọ eniyan,ó sì ń yẹ̀ wọ́n wò.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 11

Wo Orin Dafidi 11:4 ni o tọ