Orin Dafidi 110:1 BM

1 OLUWA wí fún oluwa mi, ọba, pé,“Jókòó sí apá ọ̀tún mi,títí tí n óo fi sọ àwọn ọ̀tá rẹdi àpótí ìtìsẹ̀ rẹ.”

Ka pipe ipin Orin Dafidi 110

Wo Orin Dafidi 110:1 ni o tọ