1 Ẹ yin OLUWA!Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí ó bẹ̀rù OLUWA,tí inú rẹ̀ sì dùn lọpọlọpọ sí òfin rẹ̀.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 112
Wo Orin Dafidi 112:1 ni o tọ