Orin Dafidi 112:5 BM

5 Yóo máa dára fún ẹni tí ó bá lójú àánú, tí ó sì ń yáni ní nǹkan,tí ó ń ṣe ẹ̀tọ́ ní gbogbo ọ̀nà.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 112

Wo Orin Dafidi 112:5 ni o tọ