1 Ògo kì í ṣe fún wa, OLUWA, Kì í ṣe fún wa,orúkọ rẹ nìkan ṣoṣo ni kí á yìn lógo,nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀, ati nítorí òtítọ́ rẹ.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 115
Wo Orin Dafidi 115:1 ni o tọ