Orin Dafidi 117:2 BM

2 Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ tóbi sí wa,òtítọ́ rẹ̀ sì wà títí laelae.Ẹ máa yin OLUWA.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 117

Wo Orin Dafidi 117:2 ni o tọ