42 Nígbà náà ni n óo lè dá àwọn tí ń gàn mí lóhùn,nítorí mo gbẹ́kẹ̀lé ọ̀rọ̀ rẹ.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 119
Wo Orin Dafidi 119:42 ni o tọ