Orin Dafidi 119:74 BM

74 Inú àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ yóo máa dùnnígbà tí wọ́n bá rí mi,nítorí pé mo ní ìrètí ninu ọ̀rọ̀ rẹ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 119

Wo Orin Dafidi 119:74 ni o tọ