Orin Dafidi 12:5 BM

5 OLUWA wí pé, “Nítorí ìnira àwọn aláìṣẹ̀,ati nítorí ìkérora àwọn tí à ń pọ́n lójú,n óo dìde nisinsinyii,n óo sì dáàbò bò wọ́n bí ọkàn wọn ti ń fẹ́.”

Ka pipe ipin Orin Dafidi 12

Wo Orin Dafidi 12:5 ni o tọ