4 Ọfà mímú ni a óo ta yín,a óo sì dáná sun yín.
5 Mo gbé! Nítorí pé mo dàbí àlejò tó wọ̀ ní Meṣeki,tí ń gbé ààrin àwọn àgọ́ Kedari.
6 Ó pẹ́ jù tí mo tí ń bá àwọn tí ó kórìíra alaafia gbé.
7 Alaafia ni èmi fẹ́,ṣugbọn nígbà tí mo bá sọ̀rọ̀, ìjà ṣá ni tiwọn.