Orin Dafidi 126:2 BM

2 Ẹ̀rẹ̀kẹ́ wa kún fún ẹ̀rín, a sì kọrin ayọ̀,nígbà náà ni àwọn orílẹ̀-èdè yòókù ń wí pé,“OLUWA mà ṣe nǹkan ńlá fún àwọn eniyan yìí!”

Ka pipe ipin Orin Dafidi 126

Wo Orin Dafidi 126:2 ni o tọ