3 Aya rẹ yóo dàbí àjàrà eléso pupọ ninu ilé rẹ;bí ọmọ tií yí igi olifi ká,ni àwọn ọmọ rẹ yóo yí tabili oúnjẹ rẹ ká.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 128
Wo Orin Dafidi 128:3 ni o tọ