1 Ninu ìṣòro ńlá ni mò ń ké pè ọ́, OLUWA!
2 OLUWA, gbóhùn mi,dẹtí sí ohùn ẹ̀bẹ̀ mi.
3 Bí OLUWA bá ń sàmì ẹ̀ṣẹ̀,ta ló lè yege?
4 Ṣugbọn ní ìkáwọ́ rẹ ni ìdáríjì wà,kí á lè máa bẹ̀rù rẹ.