Orin Dafidi 132:12 BM

12 Bí àwọn ọmọ rẹ bá pa majẹmu mi mọ́,tí wọ́n sì tẹ̀lé ìlànà tí n óo fi lélẹ̀ fún wọn,àwọn ọmọ tiwọn náà óo jókòó lórí ìtẹ́ rẹ títí lae.”

Ka pipe ipin Orin Dafidi 132

Wo Orin Dafidi 132:12 ni o tọ