Orin Dafidi 136:2 BM

2 Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun tí ó ju gbogbo àwọn oriṣa lọ,nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 136

Wo Orin Dafidi 136:2 ni o tọ