2 OLUWA bojú wo ilẹ̀, láti ọ̀run wá,ó wo àwọn ọmọ eniyan,láti mọ̀ bí àwọn kan bá wà tí wọ́n gbọ́n,tí wọn ń wá Ọlọrun.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 14
Wo Orin Dafidi 14:2 ni o tọ