Orin Dafidi 140:13 BM

13 Dájúdájú, àwọn olódodo yóo máa fi ọpẹ́ fún ọ;àwọn olóòótọ́ yóo sì máa gbé níwájú rẹ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 140

Wo Orin Dafidi 140:13 ni o tọ