Orin Dafidi 143:1 BM

1 OLUWA, gbọ́ adura mi;fetí sí ẹ̀bẹ̀ mi!Dá mi lóhùn ninu òtítọ́ ati òdodo rẹ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 143

Wo Orin Dafidi 143:1 ni o tọ