Orin Dafidi 144:13 BM

13 Kí àká wa kún fún oniruuru oúnjẹ,kí àwọn aguntan wa bí ẹgbẹẹgbẹrun,àní, ẹgbẹẹgbaarun ninu pápá oko wa.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 144

Wo Orin Dafidi 144:13 ni o tọ