Orin Dafidi 144:15 BM

15 Ayọ̀ ń bẹ fún orílẹ̀-èdè tí ó ní irú ibukun yìí;ayọ̀ ń bẹ fún orílẹ̀-èdè tí OLUWA jẹ́ Ọlọrun wọn.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 144

Wo Orin Dafidi 144:15 ni o tọ