5 Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí ó fi Ọlọrun Jakọbu ṣe olùrànlọ́wọ́ rẹ̀,tí ó gbójú lé OLUWA, Ọlọrun rẹ̀.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 146
Wo Orin Dafidi 146:5 ni o tọ