Orin Dafidi 146:8 BM

8 A máa la ojú àwọn afọ́jú,a máa gbé àwọn tí a tẹrí wọn ba dúró;ó fẹ́ràn àwọn olódodo.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 146

Wo Orin Dafidi 146:8 ni o tọ