3 Ẹni tí kò fi ahọ́n rẹ̀ sọ̀rọ̀ eniyan lẹ́yìn,tí kò ṣe ibi sí ẹnìkejì rẹ̀,tí kò sì sọ ọ̀rọ̀ ẹ̀gàn nípa aládùúgbò rẹ̀.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 15
Wo Orin Dafidi 15:3 ni o tọ