Orin Dafidi 16:8 BM

8 Mò ń wo OLUWA ní iwájú mi nígbà gbogbo,nítorí pé Ọlọrun dúró tì mí, ẹsẹ̀ mi kò ní yẹ̀.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 16

Wo Orin Dafidi 16:8 ni o tọ