Orin Dafidi 17:1 BM

1 Gbọ́ tèmi OLUWA, àre ni ẹjọ́ mi;fi ìtara gbọ́ igbe mi.Fetí sí adura mi nítorí kò sí ẹ̀tàn ní ẹnu mi.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 17

Wo Orin Dafidi 17:1 ni o tọ