Orin Dafidi 17:3 BM

3 Yẹ ọkàn mi wò; bẹ̀ mí wò lóru.Dán mi wò, o kò ní rí ohun burúkú kan;n kò ní fi ẹnu mi dẹ́ṣẹ̀.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 17

Wo Orin Dafidi 17:3 ni o tọ