Orin Dafidi 18:15 BM

15 Nígbà náà ni ìsàlẹ̀ òkun hàn ketekete,ìpìlẹ̀ ayé sì fojú hàn gbangba nítorí ìbáwí rẹ, OLUWA,ati nítorí agbára èémí ihò imú rẹ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 18

Wo Orin Dafidi 18:15 ni o tọ