Orin Dafidi 18:27 BM

27 Nítorí tí o máa ń gba àwọn onírẹ̀lẹ̀ là,ṣugbọn o máa ń rẹ àwọn onigbeeraga sílẹ̀.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 18

Wo Orin Dafidi 18:27 ni o tọ