Orin Dafidi 21:13 BM

13 A gbé ọ ga, nítorí agbára rẹ, OLUWA!A óo máa kọrin, a óo sì máa yin agbára rẹ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 21

Wo Orin Dafidi 21:13 ni o tọ