Orin Dafidi 21:9 BM

9 O óo jó wọn run bí iná ìléru, nígbà tí o bá yọ sí wọn.OLUWA yóo gbé wọn mì ninu ibinu rẹ̀;iná yóo sì jó wọn ní àjórun.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 21

Wo Orin Dafidi 21:9 ni o tọ