Orin Dafidi 22:27 BM

27 Gbogbo ayé ni yóo ranti OLUWAwọn yóo sì pada sọ́dọ̀ rẹ̀;gbogbo ẹ̀yà àwọn orílẹ̀-èdèni yóo sì júbà níwájú rẹ̀.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 22

Wo Orin Dafidi 22:27 ni o tọ